ThatQuiz Test Library Take this test now
JSS2 YORUBA 3RD TERM EXAM
Contributed by: College
  • 1. _________ ni itunmo ede kan si omiran
A) Ibanisoro
B) Aayan ogbufo
C) Iranra eni lowo
D) Isunki
  • 2. Eni ti o n tumo ede kan si omiran ni a n pe ni
A) Ogbufo
B) Alaroye
C) Elejo
D) Alalaye
  • 3. E ni fe tunmo oro gbodo____
A) Buru
B) Lowo
C) Gbo ede mejeeji daradara
D) Lohun
  • 4. Ni nu aayan ogbufo,a gbodo fun oro ni
A) Itunmo ti o jin na si
B) Itunmo ti ko ye rara
C) Itunmo ti o tobi
D) Itunmo ti o bamu
  • 5. Itunmo 'Boundary' ni
A) Ise
B) Ibikan
C) Aala
D) Ile
  • 6. Itunmo 'Culture' ni
A) Esin
B) Aaye
C) Iwa
D) Asa
  • 7. Itunmo 'overlap' ni
A) Ge ara won
B) Bu ara won
C) Wonu ara won
D) Na ara won
  • 8. 'He was ashamed' tunmo si
A) Oju tii
B) Oju e ri
C) Won doju ti
D) Oju n dun
  • 9. ________ ni a fi n ke ' Ewi'
A) Enu
B) Imu
C) Emi
D) Oju
  • 10. A ma n lo 'Ewi' nibi ________
A) Oro aje
B) Ayeye
C) Ogun
D) Ija
  • 11. Ki aranmo to le wa ye,_______
A) Faweeli meji gbodo te le ara won
B) Faweeli ko gbodo bere oro na
C) Konsonanti meji gbodo te le ara won
D) Ko gbodo si faweeli ninu oro na
  • 12. Se isunki oro yii : ile + iwe
A) Ilewe
B) Ilewe
C) Iluwe
D) Ileiwe
  • 13. Gba + ise
A) Gbaise
B) Gbise
C) Gbase
D) Gbese
  • 14. Ninu ewi "ise logun ise" Ohun ti a ba fara sise fun________
A) Ni pe lowo eni
B) Ni se iku pani
C) Ni so nu lowo eni
D) Ni fi iya je ni
  • 15. Apa lara ________
A) Orunkun la ba mo
B) Igunpa ni iyekan
C) Ori la ba bo
D) Igunpa la ko mo
  • 16. Eko n so ni di_______
A) Janduku
B) Oga
C) Opuro
D) Omose
  • 17. Iro ti o ni agbara lati yi iro miran pada si tire ni________
A) Aranmo kikun
B) Iro agbaranmo
C) Aranmo aforu
D) Iro afaranmo
  • 18. Iro ti o yi pada gba abuda iro miran ni
A) Iro agbaramo
B) Iparoje
C) Isunki
D) Iro afaranmo
  • 19. Omobinrin ti o gbe ibi korun ni_____
A) Aina
B) Ibikunle
C) Eli
D) Ayan
  • 20. Omo ti iya re ko se nkan osu ti won fi bi ni
A) Odun
B) Dada
C) Ilori
D) Ojo
  • 21. Omo ti oyun re ju osu mesan lo ti won fi bi ni
A) Ige
B) Ajayi
C) Oke
D) Omope
  • 22. Omo ti o yi ara mo inu apo ni
A) Oke
B) Ige
C) Ola
D) Odu
  • 23. Apeere oruko idile "Onilu" ni
A) Olalomi
B) Ogungbemi
C) Ayangbade
D) Osuntoke
  • 24. Apeere oruko amu torunwa ni
A) Kehinde
B) Gbemisola
C) Omoyeni
D) Lamidi
  • 25. Apeere oruko Abiku ni
A) Ige
B) Idowu
C) Malomo
D) Tope
  • 26. Apeere oriki ni
A) Alabi
B) Omotunde
C) Odun
D) Ojo
  • 27. ________ wa ninu awon eelo isomoloruko
A) Omigbona
B) Alubose
C) Ororo
D) Omitutu
  • 28. Ni aye atijo ojo ___ ni a maa n so omobirin loruko
A) Kewa
B) Kejo
C) Kesan
D) Keje
  • 29. Ni aye atijo, awon okunrin ni won ma n so loruko ni ojo
A) Keta
B) Kesan
C) Keje
D) Kejo
  • 30. Ninu ewi "iwulo eko" Iwulo eko ju_________ lo
A) Omo bibi lo
B) Oja ti ta lo
C) Ile kiko
D) Orun si sun lo
  • 31. Eko n so ni di
A) Jagidijagan
B) Ilumoka laye
C) Eni yepere
D) Olosi
  • 32. Iwa ika tunmo si
A) Iwa alalubarika
B) Iwa buburu
C) Iwa igberaga
D) Iwa afojudi
  • 33. Lara iwa ika ni
A) Egbe alafowosowopo
B) Ikonileru
C) Ere idaraya
D) Eko kiko
  • 34. A le dekun iwa ibaje
A) Ti a ba lowo lowo
B) Ti a ba fe iyawo pupo
C) Ti a ba bi omo pupo
D) Ti a ba fi ara wa si ipo omo lakeji
  • 35. _________ nia fi n so oro meji papo ninu gbolohun
A) Oro asopo
B) Oro ise
C) Oro aropo oruko
D) Oro atokun
  • 36. Apeere oro atokun ni
A) Sun
B) Si
C) Olu
D) Iwo
  • 37. Apeere oro - ise ni
A) Fiofio
B) Dide
C) Awon
D) Ati
  • 38. Apeere oro - oruko ni
A) Ati
B) Ibadan
C) Sugbon
D) Emi
  • 39. Dudu gidigidi"je
A) Oro ise
B) Oro atokum
C) Oro apejuwe
D) Oro oruko
  • 40. Silebu melo lowa ninu oro wonyii "0luponmita"
A) Merii7
B) Marun
C) Mee
D) Mefa
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.