ThatQuiz Test Library Take this test now
Yoruba jss2 second term exam
Contributed by: College
  • 1. Ninu ewi " ikanju" ikanju àti _________, ògbòògba ni se
A) Wahala
B) Ariwo
C) Pele
D) Ija
  • 2. E so Pele ni _________ gba
A) Aye
B) Oorun
C) Ariwo
D) Ounje
  • 3. Pa ri oro yìí," " isé síse bí eru , ________
A) N so ni di olowo
B) N pani
C) Fun ni alaafia
D) Ko la ni
  • 4. Akewi ni kí akẹẹkọ ma se Suuru, ki o ma ba ___________,
A) Ki o lẹ bá gbá maaki rẹpẹtẹ
B) Se déédéé pankere jije
C) So òwò nu
D) Ki inu re le dun
  • 5. Kìràkìtà o ________
A) O dara
B) Lewu
C) Mola
D) Mo alejo
  • 6. Ninu "ewì ipanle"ipata ọmọ kii
A) Dagba
B) Ni iyawo
C) Tete rowo mu laye
D) Lagbara
  • 7. Ipata ọmọ tó pẹ láyé, _________ lowa
A) Oko
B) Oke okun
C) Ewon
D) Ile
  • 8. Pari oro yìí, "ọmọ lile ronú e wo, _________________
A) Ko o ma ba kabamo
B) Ki o lẹ di gbajumo
C) Ki o lẹ di olowo laye
D) Ki inu re le dun
  • 9. __________, lere ipanle
A) Ounje pupo
B) Owo
C) Ofo
D) Ipo giga
  • 10. "Pokii" tunmọ sii
A) E ni ti ìya ti yi mo lara
B) Oloselu
C) Oluko
D) Agbalagba
  • 11. "Iro" tunmọ sí
A) Ẹgbẹ
B) Ará orílè-èdè
C) Onisowo
D) Ọmọ iya
  • 12. Ere ti a ma n se lẹyin isẹ ọjọ wa ni
A) Ere takasufe
B) Ere ija
C) Ere kanpakanpa
D) Ere idaraya
  • 13. Apere ere ìdárayá ni iwọnyi ayafi
A) Ere oṣupa
B) Ere gbetigbeti
C) Ere ijakadi
D) Ere bojuboju
  • 14. Ọkan lára ipa ti orin kó nínu ere idaraya ni
A) Eke sise
B) Ole
C) Ẹkọ asa
D) Ebu bibu
  • 15. Pa ri owe yii, "ile la wo,_________",
A) Ki a to Lu omo
B) Ki a to bimo
C) Ki a to gbe omo
D) Ki a to ṣọmọ loruko
  • 16. Àwon nkan ti a man wo fun Omo loruko ni iwonyi , aya fi
A) Ile
B) Aso
C) Ipo
D) Ise
  • 17. "Yetunde " je apeere oruko
A) Inagije
B) Amutorunwa
C) Abiso
D) Oriki
  • 18. Taye àti kehinde je oruko
A) Amutorunwa
B) Asopo
C) Oriki
D) Abiso
  • 19. Ìdòwú je oruko ọmọ ti ọ tẹlẹ
A) Ige
B) Ojo
C) Ibeji
D) Alaba
  • 20. Eta oko ni ọmọ
A) Ti A bi sè iketa ibeji
B) Ti o tele ojo
C) Orí omi
D) Inu igi
  • 21. Ọmọ ti o wetabi ẹsẹ ni
A) Olugbodi
B) Ojo
C) Abiona
D) Erinle
  • 22. Ọmọ ti o dójú bọlé ni
A) Amope
B) Odu
C) ilori
D) Ajayi
  • 23. Ọmọ ti o yí ra mọ apo ni
A) Ola
B) Odu
C) Ilori
D) Oke
  • 24. Ọmọ ti ìya rè ko se nkan osu ti wọn fí bi ni
A) Aina
B) Yewande
C) Ilori
D) Iyabo
  • 25. Ewo ni kii se oruko oriki nínú iwonyii
A) Akanji
B) Ajao
C) Ajayi
D) Adio
  • 26. Àpẹẹrẹ oruko abiku ni iwọnyi ayafi
A) Bamiji
B) Banjoko
C) Bantale
D) Bamidele
  • 27. E wo ni oruko ìdílé onilu nínú iwonyii
A) Okewale
B) Adewale
C) Ayanwale
D) Olawale
  • 28. E wo ni oruko ìdílé eleegun nínú àwon oruko wonyi
A) Ogunyemi
B) Ifabunmi
C) Olorode
D) Ojelade
  • 29. Osù + oṣù =
A) Osousu
B) Osuosu
C) Osoosu
D) Osuusu
  • 30. Osan +Osan
A) Osonson
B) Osoosan
C) Osansan
D) Osunsun
  • 31. Pe eja + pe eja
A) Pejaapejaa
B) Pejapeja
C) Peejapeeja
D) Pajápajá
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.